Adedotun Aremu Gbadebo III

Alake

Adedotun Gbadebo
Alake of Egba
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
2 August 2005
AsíwájúOba Oyebade Lipede
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí14 Oṣù Kẹ̀sán 1943 (1943-09-14)
Abeokuta

Adedotun Aremu Gbadebo lll (tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹsan ọdún 1943) ní Aláké ti ilẹ̀ Ẹ̀gbá lọwọlọwọ bayi. Ẹ̀gbá jẹ́ ẹ̀yà kan ní ìlú [[Abẹ́òkuta]], orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó ti wà lórí oyè láti ọjọ́ kejì oṣù kẹjọ ọdún 2005.


From Wikipedia, the free encyclopedia · View on Wikipedia

Developed by Tubidy